here are things that new Muslim must learn and know, including knowing the answer to the three significant questions that every person is questioned after death, determining his eternal destiny; either to Paradise or Hell, they are:
- Who is your lord?
- What is your religion?
- Who is your Prophet?
Awọn ipilẹ ti ko si ibuyẹ lati ma mọ wọn:
Ti o ba wọnu Isilaamu, awọn ipilẹ kan n bẹ ti kikọ rẹ ati nini imọ nipa ẹ jẹ dandan fun ẹ, ninu iyẹn ni mimọ idahun awọn ibeere mẹta to ṣe pataki to ṣe pe wọn maa bi gbogbo eniyan lẹyin iku, to si ṣe pe oun ni yoo sọ bi ìkángun gbere rẹ ṣe maa ri; boya lọ si inu alujanna ni tabi lọ si inu ina, awọn naa ni:
- Ta ni Olúwa rẹ
- Ki ni ẹsin rẹ
- Ta ni Anọbi rẹ