My first day in Islam: A simplified explanation of the Three principles that a new Muslim must know

 

here are things that new Muslim must learn and know, including knowing the answer to the three significant questions that every person is questioned after death, determining his eternal destiny; either to Paradise or Hell, they are:
- Who is your lord? 

- What is your religion? 

- Who is your Prophet? 

 

Ọjọ àkọ́kọ́ mi ninu IsilaamuAlaye ti o rọrun fun awọn ìpìlẹ̀ mẹta ti Musulumi titun gbọdọ mọẸni

 

Awọn ipilẹ ti ko si ibuyẹ lati ma mọ wọn:

Ti o ba wọnu Isilaamu, awọn ipilẹ kan n bẹ ti kikọ rẹ ati nini imọ nipa ẹ jẹ dandan fun ẹ, ninu iyẹn ni mimọ idahun awọn ibeere mẹta to ṣe pataki to ṣe pe wọn maa bi gbogbo eniyan lẹyin iku, to si ṣe pe oun ni yoo sọ bi ìkángun gbere rẹ ṣe maa ri; boya lọ si inu alujanna ni tabi lọ si inu ina, awọn naa ni:

- Ta ni Olúwa rẹ

- Ki ni ẹsin rẹ

- Ta ni Anọbi rẹ

 

Read the book in another language